Skip to content
Scan a barcode
Scan
Paperback Adura Ojojumo Ni Ede Yoruba [Yoruba] Book

ISBN: 1495347370

ISBN13: 9781495347375

Adura Ojojumo Ni Ede Yoruba [Yoruba]

Adura ni koko ati ohun ti o se pataki julo ninu igbesi aiye awa omo enia ati eda owo OLORUN. Iwe Adura Ojojumo yi wa fun gbogbo omo Yoruba pata nibi gbogbo ni ile agbaiye. E maa gb'adura ni gbogbo iseju, ni gbogbo wakati, ni gbogbo asiko ati ni gbogbo ojo aiye wa lai sinmi. Agbara wa ninu OLORUN ni oruko JESU nikan ninu okan wa ju gbogbo aniyan ati aajo lo. OLUWA yio ran wa lowo, OLORUN si ti gbo adura wa ni oruko nla ti JESU, Amin, E maa gbadura lai sinmi ni OLORUN wi. Iwe adura ojojumo yi yio ran wa lowo lati ba OLORUN rin. Maa gba adura yi tabi ka iwe yi gege bi itosona re lojojumo. Adura ni ede Yoruba a maa fi ni lokan bale a si mu inu eni dun wipe mo nba Eleda mi soro ni ede ti OLOrun fi da mi gege bi aworan ati eda Ara Re. OLORUN ye mi pupo, O si ni itumo si mi gidigidi ni ede abinibi mi. Ida keji iwe Adura yi, 500 Master Prayers wa ni ede geesi Oyinbo (English) ni Amazon.com kan na. Ma safira, tete lo ra iwe Adura mejeji yi ki o le ni imo ti o kun lekunrere ninu re, pelu ogbon ti o ye kooro wa ninu gbigba Adura ni ede Baba ati Iya re. Yoruba ati OLORUN ni ede re. Bakana ni iwe, Soul connection to GOD and Transfiguration to SPIRIT wa fun atunbi aiye re na, o wa ni Amazon.com bee gege. Ra awon iwe yi ni kiakia. Omo OLORUN, ijafara lewu. Ise OLORUN, iyanu ni. JESU yio ran gbogbo wa lowo o, amin.

Recommended

Format: Paperback

Temporarily Unavailable

We receive fewer than 1 copy every 6 months.

Save to List

Customer Reviews

0 rating
Copyright © 2026 Thriftbooks.com Terms of Use | Privacy Policy | Do Not Sell/Share My Personal Information | Cookie Policy | Cookie Preferences | Accessibility Statement
ThriftBooks ® and the ThriftBooks ® logo are registered trademarks of Thrift Books Global, LLC
GoDaddy Verified and Secured